1 Kíróníkà 29:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Nítorí àjèjì àti àlejò ni a jẹ́ níwájú rẹ, bí gbogbo àwọn baba ńlá wa ti jẹ́.+ Nítorí àwọn ọjọ́ wa lórí ilẹ̀ ayé da bí òjìji,+ kò sí ìrètí kankan. Jóòbù 14:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “Èèyàn tí obìnrin bí,Ọlọ́jọ́ kúkúrú ni,+ wàhálà* rẹ̀ sì máa ń pọ̀ gan-an.+ 2 Ó jáde wá bí ìtànná, ó sì rọ dà nù;*+Ó ń sá lọ bí òjìji, ó sì pòórá.+
15 Nítorí àjèjì àti àlejò ni a jẹ́ níwájú rẹ, bí gbogbo àwọn baba ńlá wa ti jẹ́.+ Nítorí àwọn ọjọ́ wa lórí ilẹ̀ ayé da bí òjìji,+ kò sí ìrètí kankan.
14 “Èèyàn tí obìnrin bí,Ọlọ́jọ́ kúkúrú ni,+ wàhálà* rẹ̀ sì máa ń pọ̀ gan-an.+ 2 Ó jáde wá bí ìtànná, ó sì rọ dà nù;*+Ó ń sá lọ bí òjìji, ó sì pòórá.+