Oníwàásù 12:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Bákan náà, èèyàn á máa bẹ̀rù ibi tó ga, ẹ̀rù á sì wà lójú ọ̀nà. Igi álímọ́ńdì ń yọ ìtànná,+ tata ń wọ́ ara rẹ̀ lọ, àgbáyun kápérì sì bẹ́, torí pé èèyàn ń lọ sí ilé rẹ̀ ayérayé,+ àwọn tó ń ṣọ̀fọ̀ sì ń rìn kiri ní ojú ọ̀nà;+ Oníwàásù 12:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nígbà náà, erùpẹ̀ á pa dà sí ilẹ̀,+ bó ṣe wà tẹ́lẹ̀, ẹ̀mí* á sì pa dà sọ́dọ̀ Ọlọ́run tòótọ́ tó fúnni.+
5 Bákan náà, èèyàn á máa bẹ̀rù ibi tó ga, ẹ̀rù á sì wà lójú ọ̀nà. Igi álímọ́ńdì ń yọ ìtànná,+ tata ń wọ́ ara rẹ̀ lọ, àgbáyun kápérì sì bẹ́, torí pé èèyàn ń lọ sí ilé rẹ̀ ayérayé,+ àwọn tó ń ṣọ̀fọ̀ sì ń rìn kiri ní ojú ọ̀nà;+
7 Nígbà náà, erùpẹ̀ á pa dà sí ilẹ̀,+ bó ṣe wà tẹ́lẹ̀, ẹ̀mí* á sì pa dà sọ́dọ̀ Ọlọ́run tòótọ́ tó fúnni.+