Jóòbù 10:21, 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Kí n tó lọ, tí mi ò sì ní pa dà wá,+Sí ilẹ̀ tó ṣókùnkùn biribiri,*+22 Sí ilẹ̀ tí ìṣúdùdù rẹ̀ pọ̀ gidigidi,Ilẹ̀ tó ṣókùnkùn biribiri, tó sì rí rúdurùdu,Níbi tí ìmọ́lẹ̀ pàápàá ti dà bí òkùnkùn.”
21 Kí n tó lọ, tí mi ò sì ní pa dà wá,+Sí ilẹ̀ tó ṣókùnkùn biribiri,*+22 Sí ilẹ̀ tí ìṣúdùdù rẹ̀ pọ̀ gidigidi,Ilẹ̀ tó ṣókùnkùn biribiri, tó sì rí rúdurùdu,Níbi tí ìmọ́lẹ̀ pàápàá ti dà bí òkùnkùn.”