-
Jóòbù 14:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Bí omi ṣe ń mú kí òkúta yìnrìn,
Tí ọ̀gbàrá rẹ̀ sì ń wọ́ iyẹ̀pẹ̀ ilẹ̀.
Bẹ́ẹ̀ lo ṣe sọ ìrètí ẹni kíkú dòfo.
-
-
Jóòbù 19:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ó wó mi lulẹ̀ yí ká títí mo fi ṣègbé;
Ó sì fa ìrètí mi tu bí igi.
-