ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 12:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Àgọ́ àwọn olè wà ní àlàáfíà,+

      Àwọn tó sì ń mú Ọlọ́run bínú wà láìséwu,+

      Àwọn tí ọlọ́run wọn wà ní ọwọ́ wọn.

  • Sáàmù 37:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Dákẹ́ jẹ́ẹ́ níwájú Jèhófà+

      Kí o sì dúró* dè é.

      Má banú jẹ́ nítorí ẹni

      Tó gbèrò ibi, tó sì mú un ṣẹ.+

  • Sáàmù 73:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Nítorí mo jowú àwọn agbéraga*

      Nígbà tí mo rí àlàáfíà àwọn ẹni burúkú.+

  • Sáàmù 73:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Bí ọ̀rọ̀ àwọn ẹni burúkú ṣe rí nìyí, àwọn tí gbogbo nǹkan dẹrùn fún.+

      Wọ́n ń kó ọrọ̀ jọ ṣáá.+

  • Jeremáyà 12:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Olódodo ni ọ́, Jèhófà,+ nígbà tí mo gbé ẹjọ́ mi wá sọ́dọ̀ rẹ,

      Nígbà tí mo sọ nípa ìdájọ́ òdodo fún ọ.

      Àmọ́ kí nìdí tí ọ̀nà àwọn ẹni burúkú fi ń yọrí sí rere,+

      Kí sì nìdí tí ọkàn àwọn oníbékebèke fi balẹ̀?

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́