Jóòbù 21:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Kí ló dé tí àwọn ẹni burúkú ṣì fi wà láàyè,+Tí wọ́n ń darúgbó, tí wọ́n sì ń di ọlọ́rọ̀?*+ Jeremáyà 12:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Olódodo ni ọ́, Jèhófà,+ nígbà tí mo gbé ẹjọ́ mi wá sọ́dọ̀ rẹ,Nígbà tí mo sọ nípa ìdájọ́ òdodo fún ọ. Àmọ́ kí nìdí tí ọ̀nà àwọn ẹni burúkú fi ń yọrí sí rere,+Kí sì nìdí tí ọkàn àwọn oníbékebèke fi balẹ̀?
12 Olódodo ni ọ́, Jèhófà,+ nígbà tí mo gbé ẹjọ́ mi wá sọ́dọ̀ rẹ,Nígbà tí mo sọ nípa ìdájọ́ òdodo fún ọ. Àmọ́ kí nìdí tí ọ̀nà àwọn ẹni burúkú fi ń yọrí sí rere,+Kí sì nìdí tí ọkàn àwọn oníbékebèke fi balẹ̀?