Sáàmù 73:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nítorí mo jowú àwọn agbéraga*Nígbà tí mo rí àlàáfíà àwọn ẹni burúkú.+ Sáàmù 73:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ìdààmú tó ń bá àwọn èèyàn yòókù kì í bá wọn,+Ìyà tó sì ń jẹ àwọn èèyàn tó kù kì í jẹ wọ́n.+