ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 4:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Élífásì+ ará Témánì wá fèsì pé:

  • Jóòbù 15:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Élífásì+ ará Témánì fèsì pé:

  • Jóòbù 22:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Élífásì+ ará Témánì fèsì pé:

  • Jóòbù 42:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Lẹ́yìn tí Jèhófà bá Jóòbù sọ àwọn ọ̀rọ̀ yìí, Jèhófà sọ fún Élífásì ará Témánì pé:

      “Inú ń bí mi gidigidi sí ìwọ àtàwọn ọ̀rẹ́ rẹ méjèèjì,+ torí ẹ ò sọ òtítọ́ nípa mi,+ bí ìránṣẹ́ mi Jóòbù ṣe sọ òtítọ́.

  • Jóòbù 42:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Nítorí náà, Élífásì ará Témánì, Bílídádì ọmọ Ṣúáhì àti Sófárì ọmọ Náámà lọ ṣe ohun tí Jèhófà sọ fún wọn pé kí wọ́n ṣe. Jèhófà sì gbọ́ àdúrà Jóòbù.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́