-
Jóòbù 31:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Tó bá jẹ́ ọrọ̀ rẹpẹtẹ+ tí mo ní ló ń fún mi láyọ̀,
Torí mo ti kó ọ̀pọ̀ ohun ìní jọ;+
-
Jóòbù 31:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Ẹ̀ṣẹ̀ tí àwọn adájọ́ gbọ́dọ̀ torí ẹ̀ jẹni níyà ni,
Torí màá ti fìyẹn sẹ́ Ọlọ́run tòótọ́ lókè.
-
-
-