Jóòbù 1:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jèhófà sì bi Sátánì pé: “Ṣé o ti kíyè sí* Jóòbù ìránṣẹ́ mi? Kò sí ẹni tó dà bíi rẹ̀ ní ayé. Olódodo àti olóòótọ́* èèyàn+ ni, ó bẹ̀rù Ọlọ́run, ó sì kórìíra ohun tó burú.” Sáàmù 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Nítorí Jèhófà mọ ọ̀nà àwọn olódodo,+Àmọ́ ọ̀nà àwọn èèyàn burúkú máa ṣègbé.+ Sáàmù 139:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 139 Jèhófà, o ti yẹ̀ mí wò látòkè délẹ̀, o sì mọ̀ mí.+
8 Jèhófà sì bi Sátánì pé: “Ṣé o ti kíyè sí* Jóòbù ìránṣẹ́ mi? Kò sí ẹni tó dà bíi rẹ̀ ní ayé. Olódodo àti olóòótọ́* èèyàn+ ni, ó bẹ̀rù Ọlọ́run, ó sì kórìíra ohun tó burú.”