-
Diutarónómì 24:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Gbàrà tí oòrùn bá wọ̀ ni kí o rí i pé o dá ohun tó fi ṣe ìdúró pa dà fún un, kó lè rí aṣọ fi sùn,+ á sì súre fún ọ; èyí á sì jẹ́ òdodo lójú Jèhófà Ọlọ́run rẹ.
-