Jóòbù 15:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Kí ni ẹni kíkú jẹ́ tó fi máa mọ́,Tàbí ẹnikẹ́ni tí obìnrin bí tó fi máa jẹ́ olódodo?+ 15 Wò ó! Kò ní ìgbàgbọ́ nínú àwọn ẹni mímọ́ rẹ̀,Àwọn ọ̀run pàápàá kò mọ́ ní ojú rẹ̀.+
14 Kí ni ẹni kíkú jẹ́ tó fi máa mọ́,Tàbí ẹnikẹ́ni tí obìnrin bí tó fi máa jẹ́ olódodo?+ 15 Wò ó! Kò ní ìgbàgbọ́ nínú àwọn ẹni mímọ́ rẹ̀,Àwọn ọ̀run pàápàá kò mọ́ ní ojú rẹ̀.+