Jóòbù 16:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Mo ti gbọ́ ọ̀pọ̀ nǹkan báyìí rí. Olùtùnú tó ń dani láàmú ni gbogbo yín!+ 3 Ṣé àwọn ọ̀rọ̀ asán* lópin ni? Kí ló ń bí ẹ nínú tí o fi ń fèsì báyìí?
2 “Mo ti gbọ́ ọ̀pọ̀ nǹkan báyìí rí. Olùtùnú tó ń dani láàmú ni gbogbo yín!+ 3 Ṣé àwọn ọ̀rọ̀ asán* lópin ni? Kí ló ń bí ẹ nínú tí o fi ń fèsì báyìí?