Rúùtù 1:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ó sì ń fèsì pé: “Ẹ má pè mí ní Náómì* mọ́. Márà* ni kí ẹ máa pè mí, torí Olódùmarè ti mú kí ayé mi korò gan-an.+ 2 Àwọn Ọba 4:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Nígbà tó dé ọ̀dọ̀ èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ ní òkè náà, ní kíá, ó di ẹsẹ̀ rẹ̀ mú.+ Ni Géhásì bá sún mọ́ ọn láti tì í kúrò, àmọ́ èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ sọ pé: “Fi sílẹ̀, ẹ̀dùn ọkàn ló bá a,* Jèhófà ò sì jẹ́ kí n mọ̀, bẹ́ẹ̀ ni kò sọ fún mi.”
20 Ó sì ń fèsì pé: “Ẹ má pè mí ní Náómì* mọ́. Márà* ni kí ẹ máa pè mí, torí Olódùmarè ti mú kí ayé mi korò gan-an.+
27 Nígbà tó dé ọ̀dọ̀ èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ ní òkè náà, ní kíá, ó di ẹsẹ̀ rẹ̀ mú.+ Ni Géhásì bá sún mọ́ ọn láti tì í kúrò, àmọ́ èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ sọ pé: “Fi sílẹ̀, ẹ̀dùn ọkàn ló bá a,* Jèhófà ò sì jẹ́ kí n mọ̀, bẹ́ẹ̀ ni kò sọ fún mi.”