-
Sáàmù 148:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ẹ̀yin mànàmáná àti yìnyín ńlá, yìnyín kéékèèké àti ojú ọ̀run tó ṣú bolẹ̀,
Ìwọ ìjì líle, tó ń mú ọ̀rọ̀ rẹ̀ ṣẹ,+
-
Oníwàásù 1:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ẹ̀fúùfù ń lọ sí gúúsù, ó sì ń yí lọ sí àríwá;
Yíyí ló ń yí po nígbà gbogbo; ẹ̀fúùfù ń yí po ṣáá.
-
-
-