-
Ẹ́kísódù 9:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Mósè wá na ọ̀pá rẹ̀ sí ọ̀run, Jèhófà sì mú kí ààrá sán, yìnyín bọ́, iná* sọ̀ kalẹ̀, Jèhófà sì ń mú kí òjò yìnyín rọ̀ sórí ilẹ̀ Íjíbítì.
-
-
Sáàmù 107:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Bó ṣe fi ọ̀rọ̀ rẹ̀ mú kí ìjì máa jà,+
Tó sì ń ru ìgbì òkun sókè.
-