Sáàmù 18:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nígbà náà, Jèhófà bẹ̀rẹ̀ sí í sán ààrá ní ọ̀run;+Ẹni Gíga Jù Lọ mú kí a gbọ́ ohùn rẹ̀+Pẹ̀lú yìnyín àti ẹyin iná.
13 Nígbà náà, Jèhófà bẹ̀rẹ̀ sí í sán ààrá ní ọ̀run;+Ẹni Gíga Jù Lọ mú kí a gbọ́ ohùn rẹ̀+Pẹ̀lú yìnyín àti ẹyin iná.