Sáàmù 6:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ṣojú rere sí mi,* Jèhófà, nítorí ó ti ń rẹ̀ mí. Wò mí sàn, Jèhófà,+ nítorí àwọn egungun mi ń gbọ̀n.
2 Ṣojú rere sí mi,* Jèhófà, nítorí ó ti ń rẹ̀ mí. Wò mí sàn, Jèhófà,+ nítorí àwọn egungun mi ń gbọ̀n.