Sáàmù 41:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Mo sọ pé: “Jèhófà, ṣojú rere sí mi.+ Wò mí* sàn,+ torí mo ti ṣẹ̀ sí ọ.”+ Sáàmù 103:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jẹ́ kí n* yin Jèhófà;Kí n má gbàgbé gbogbo ohun tó ti ṣe láé.+ 3 Ó ń dárí gbogbo àṣìṣe mi jì mí,+Ó sì ń wo gbogbo àìsàn mi sàn;+
2 Jẹ́ kí n* yin Jèhófà;Kí n má gbàgbé gbogbo ohun tó ti ṣe láé.+ 3 Ó ń dárí gbogbo àṣìṣe mi jì mí,+Ó sì ń wo gbogbo àìsàn mi sàn;+