ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 15:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Ó sọ pé: “Tí ẹ bá ṣègbọràn sí ohùn Jèhófà Ọlọ́run yín délẹ̀délẹ̀, tí ẹ ṣe ohun tó tọ́ ní ojú rẹ̀, tí ẹ pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́, tí ẹ sì ń tẹ̀ lé gbogbo ìlànà rẹ̀,+ mi ò ní mú kí ìkankan ṣe yín nínú àwọn àrùn tí mo mú kó ṣe àwọn ará Íjíbítì,+ torí èmi Jèhófà ló ń mú yín lára dá.”+

  • Sáàmù 41:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Jèhófà yóò fún un lókun lórí ibùsùn àìsàn rẹ̀;+

      Ìwọ yóò pààrọ̀ ibùsùn rẹ̀ nígbà tó ń ṣàìsàn.

  • Sáàmù 147:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ó ń mú àwọn tó ní ọgbẹ́ ọkàn lára dá;

      Ó ń di àwọn egbò wọn.

  • Àìsáyà 33:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Kò sí ẹnì kankan tó ń gbé ibẹ̀* tó máa sọ pé: “Ara mi ò yá.”+

      A ti máa dárí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn èèyàn tó ń gbé ilẹ̀ náà jì wọ́n.+

  • Jémíìsì 5:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Àdúrà ìgbàgbọ́ sì máa mú aláìsàn náà* lára dá, Jèhófà* máa gbé e dìde. Tó bá sì ti dẹ́ṣẹ̀, a máa dárí jì í.

  • Ìfihàn 21:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Ó máa nu gbogbo omijé kúrò ní ojú wọn,+ ikú ò ní sí mọ́,+ kò ní sí ọ̀fọ̀ tàbí ẹkún tàbí ìrora mọ́.+ Àwọn nǹkan àtijọ́ ti kọjá lọ.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́