Àìsáyà 35:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àwọn tí Jèhófà rà pa dà máa pa dà wá,+ wọ́n sì máa kígbe ayọ̀ wá sí Síónì.+ Ayọ̀ tí kò lópin máa dé orí wọn ládé.+ Wọ́n á máa yọ̀ gidigidi, inú wọn á sì máa dùn,Ẹ̀dùn ọkàn àti ìbànújẹ́ kò ní sí mọ́.+ Àìsáyà 65:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Inú mi máa dùn nínú Jerúsálẹ́mù, màá sì yọ̀ torí àwọn èèyàn mi;+A ò ní gbọ́ igbe ẹkún tàbí igbe ìdààmú nínú rẹ̀ mọ́.”+
10 Àwọn tí Jèhófà rà pa dà máa pa dà wá,+ wọ́n sì máa kígbe ayọ̀ wá sí Síónì.+ Ayọ̀ tí kò lópin máa dé orí wọn ládé.+ Wọ́n á máa yọ̀ gidigidi, inú wọn á sì máa dùn,Ẹ̀dùn ọkàn àti ìbànújẹ́ kò ní sí mọ́.+
19 Inú mi máa dùn nínú Jerúsálẹ́mù, màá sì yọ̀ torí àwọn èèyàn mi;+A ò ní gbọ́ igbe ẹkún tàbí igbe ìdààmú nínú rẹ̀ mọ́.”+