Òwe 14:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ẹni tó bá ń fojú àbùkù wo ọmọnìkejì rẹ̀ ń dẹ́ṣẹ̀,Àmọ́ ẹni tó bá ń ṣàánú aláìní jẹ́ aláyọ̀.+ Òwe 14:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ẹni tó ń lu aláìní ní jìbìtì ń gan Ẹni tó dá a,+Àmọ́ ẹni tó ń ṣàánú tálákà ń yìn Ín lógo.+ Òwe 19:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ẹni tó ń ṣojúure sí aláìní, Jèhófà ló ń yá ní nǹkan,+Á sì san án* pa dà fún un nítorí ohun tó ṣe.+
17 Ẹni tó ń ṣojúure sí aláìní, Jèhófà ló ń yá ní nǹkan,+Á sì san án* pa dà fún un nítorí ohun tó ṣe.+