ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 15:39
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 39 ‘Kí ẹ máa ṣe wajawaja náà síbẹ̀, kí ẹ lè máa rí i, kó sì máa rán yín létí gbogbo àṣẹ Jèhófà, kí ẹ sì máa pa wọ́n mọ́.+ Ẹ ò gbọ́dọ̀ tẹ̀ lé ọkàn àti ojú yín tó ń mú kí ẹ lọ ṣe àgbèrè ẹ̀sìn.+

  • Oníwàásù 11:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Máa yọ̀, ìwọ ọ̀dọ́kùnrin, nígbà tí o ṣì jẹ́ ọ̀dọ́, sì jẹ́ kí ọkàn rẹ máa yọ̀ ní ìgbà ọ̀dọ́ rẹ. Máa ṣe ohun tí ọkàn rẹ bá sọ, sì máa lọ síbi tí ojú rẹ bá darí rẹ sí; ṣùgbọ́n mọ̀ pé Ọlọ́run tòótọ́ máa dá ọ lẹ́jọ́* lórí gbogbo nǹkan wọ̀nyí.+

  • Ìsíkíẹ́lì 6:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Àwọn tó bá yè bọ́ yóò rántí mi láàárín àwọn orílẹ̀-èdè tó kó wọn lẹ́rú.+ Wọ́n á rí i pé ó dùn mí gan-an bí ọkàn àìṣòótọ́* wọn ṣe mú kí wọ́n kẹ̀yìn sí mi+ àti bí ojú wọn ṣe mú kí ọkàn wọn fà sí àwọn òrìṣà ẹ̀gbin wọn.*+ Gbogbo iṣẹ́ ibi àtàwọn ohun ìríra tí wọ́n ti ṣe yóò kó ìtìjú bá wọn, wọ́n á sì kórìíra rẹ̀ gidigidi.+

  • Mátíù 5:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Tí ojú ọ̀tún rẹ bá ń mú ọ kọsẹ̀, yọ ọ́, kí o sì sọ ọ́ nù kúrò lọ́dọ̀ rẹ.+ Torí ó sàn kí o má ní ẹ̀yà ara kan ju kí a ju gbogbo ara rẹ sínú Gẹ̀hẹ́nà.*+

  • 1 Jòhánù 2:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 torí gbogbo ohun tó wà nínú ayé—ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara,+ ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ojú+ àti fífi ohun ìní ẹni ṣe àṣehàn*—kò wá látọ̀dọ̀ Baba, àmọ́ ó wá látọ̀dọ̀ ayé.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́