1 Sámúẹ́lì 1:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Inú Hánà bà jẹ́* gan-an, ó bẹ̀rẹ̀ sí í gbàdúrà sí Jèhófà,+ ó sì ń sunkún tẹ̀dùntẹ̀dùn. 2 Àwọn Ọba 4:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Nígbà tó dé ọ̀dọ̀ èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ ní òkè náà, ní kíá, ó di ẹsẹ̀ rẹ̀ mú.+ Ni Géhásì bá sún mọ́ ọn láti tì í kúrò, àmọ́ èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ sọ pé: “Fi sílẹ̀, ẹ̀dùn ọkàn ló bá a,* Jèhófà ò sì jẹ́ kí n mọ̀, bẹ́ẹ̀ ni kò sọ fún mi.”
27 Nígbà tó dé ọ̀dọ̀ èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ ní òkè náà, ní kíá, ó di ẹsẹ̀ rẹ̀ mú.+ Ni Géhásì bá sún mọ́ ọn láti tì í kúrò, àmọ́ èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ sọ pé: “Fi sílẹ̀, ẹ̀dùn ọkàn ló bá a,* Jèhófà ò sì jẹ́ kí n mọ̀, bẹ́ẹ̀ ni kò sọ fún mi.”