Jẹ́nẹ́sísì 18:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ní báyìí tí ẹ ti wá sọ́dọ̀ ìránṣẹ́ yín, ẹ jẹ́ kí n fún yín ní búrẹ́dì, kí ara lè tù yín.* Lẹ́yìn ìyẹn, ẹ lè máa lọ.” Torí náà, wọ́n sọ pé: “Ó dáa. O lè ṣe ohun tí o sọ.” Róòmù 12:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ẹ máa ṣàjọpín nǹkan pẹ̀lú àwọn ẹni mímọ́ kí wọ́n lè rí ohun tí wọ́n nílò.+ Ẹ máa ṣe aájò àlejò.+
5 Ní báyìí tí ẹ ti wá sọ́dọ̀ ìránṣẹ́ yín, ẹ jẹ́ kí n fún yín ní búrẹ́dì, kí ara lè tù yín.* Lẹ́yìn ìyẹn, ẹ lè máa lọ.” Torí náà, wọ́n sọ pé: “Ó dáa. O lè ṣe ohun tí o sọ.”