Jóòbù 14:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ká ní o lè fi mí pa mọ́ sínú Isà Òkú* ni,+Kí o fi mí pa mọ́ títí ìbínú rẹ fi máa kọjá,Kí o yan àkókò kan sílẹ̀ fún mi, kí o sì rántí mi!+
13 Ká ní o lè fi mí pa mọ́ sínú Isà Òkú* ni,+Kí o fi mí pa mọ́ títí ìbínú rẹ fi máa kọjá,Kí o yan àkókò kan sílẹ̀ fún mi, kí o sì rántí mi!+