Jóòbù 2:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn ọ̀rẹ́* Jóòbù mẹ́ta gbọ́ nípa gbogbo àjálù tó dé bá a, kálukú sì wá láti ibi tó ń gbé, Élífásì+ ará Témánì, Bílídádì+ ọmọ Ṣúáhì+ àti Sófárì+ ọmọ Náámà. Wọ́n ṣàdéhùn láti pàdé, kí wọ́n lè lọ bá Jóòbù kẹ́dùn, kí wọ́n sì tù ú nínú.
11 Àwọn ọ̀rẹ́* Jóòbù mẹ́ta gbọ́ nípa gbogbo àjálù tó dé bá a, kálukú sì wá láti ibi tó ń gbé, Élífásì+ ará Témánì, Bílídádì+ ọmọ Ṣúáhì+ àti Sófárì+ ọmọ Náámà. Wọ́n ṣàdéhùn láti pàdé, kí wọ́n lè lọ bá Jóòbù kẹ́dùn, kí wọ́n sì tù ú nínú.