Hébérù 11:24, 25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ìgbàgbọ́ mú kí Mósè kọ̀ kí wọ́n máa pe òun ní ọmọ ọmọbìnrin Fáráò+ nígbà tó dàgbà,+ 25 ó yàn pé kí wọ́n fìyà jẹ òun pẹ̀lú àwọn èèyàn Ọlọ́run dípò kó jẹ ìgbádùn ẹ̀ṣẹ̀ tí kì í tọ́jọ́,
24 Ìgbàgbọ́ mú kí Mósè kọ̀ kí wọ́n máa pe òun ní ọmọ ọmọbìnrin Fáráò+ nígbà tó dàgbà,+ 25 ó yàn pé kí wọ́n fìyà jẹ òun pẹ̀lú àwọn èèyàn Ọlọ́run dípò kó jẹ ìgbádùn ẹ̀ṣẹ̀ tí kì í tọ́jọ́,