-
Òwe 3:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Má ṣe jẹ́ kí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ àti ìṣòtítọ́* fi ọ́ sílẹ̀.+
So wọ́n mọ́ ọrùn rẹ;
Kọ wọ́n sí wàláà ọkàn rẹ;+
-
Òwe 19:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ ni ẹwà èèyàn;+
Ó sì sàn kéèyàn jẹ́ aláìní ju kí ó jẹ́ òpùrọ́.
-
-
-