Sáàmù 135:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó ń mú kí ìkùukùu* ròkè láti ìkángun ayé;Ó ń ṣe mànàmáná* fún òjò;Ó ń mú ẹ̀fúùfù jáde látinú àwọn ilé ìṣúra rẹ̀.+
7 Ó ń mú kí ìkùukùu* ròkè láti ìkángun ayé;Ó ń ṣe mànàmáná* fún òjò;Ó ń mú ẹ̀fúùfù jáde látinú àwọn ilé ìṣúra rẹ̀.+