Òwe 23:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nígbà tí o bá bojú wò ó, kò ní sí níbẹ̀,+Torí ó dájú pé ó máa hu ìyẹ́ bí ẹyẹ idì, á sì fò lọ sójú ọ̀run.+ Àìsáyà 40:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Àmọ́ àwọn tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà máa jèrè okun pa dà. Wọ́n máa fi ìyẹ́ fò lọ sókè réré bí ẹyẹ idì.+ Wọ́n máa sáré, okun ò ní tán nínú wọn;Wọ́n máa rìn, kò sì ní rẹ̀ wọ́n.”+
5 Nígbà tí o bá bojú wò ó, kò ní sí níbẹ̀,+Torí ó dájú pé ó máa hu ìyẹ́ bí ẹyẹ idì, á sì fò lọ sójú ọ̀run.+
31 Àmọ́ àwọn tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà máa jèrè okun pa dà. Wọ́n máa fi ìyẹ́ fò lọ sókè réré bí ẹyẹ idì.+ Wọ́n máa sáré, okun ò ní tán nínú wọn;Wọ́n máa rìn, kò sì ní rẹ̀ wọ́n.”+