Sáàmù 103:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ó ń fi ohun rere tẹ́ mi lọ́rùn+ ní gbogbo ọjọ́ ayé mi,Kí agbára* mi lè di ọ̀tun bíi ti ẹyẹ idì.+