Sáàmù 51:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Dá ayọ̀ ìgbàlà rẹ pa dà fún mi;+Kí o sì jẹ́ kó máa wù mí láti ṣègbọràn sí ọ.* Àìsáyà 40:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Àmọ́ àwọn tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà máa jèrè okun pa dà. Wọ́n máa fi ìyẹ́ fò lọ sókè réré bí ẹyẹ idì.+ Wọ́n máa sáré, okun ò ní tán nínú wọn;Wọ́n máa rìn, kò sì ní rẹ̀ wọ́n.”+
31 Àmọ́ àwọn tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà máa jèrè okun pa dà. Wọ́n máa fi ìyẹ́ fò lọ sókè réré bí ẹyẹ idì.+ Wọ́n máa sáré, okun ò ní tán nínú wọn;Wọ́n máa rìn, kò sì ní rẹ̀ wọ́n.”+