-
Sáàmù 24:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Jèhófà ló ni ayé àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀,+
Ilẹ̀ tó ń méso jáde àti àwọn tó ń gbé orí rẹ̀.
-
-
Sáàmù 50:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Ká ní ebi ń pa mí, mi ò ní sọ fún ọ,
Nítorí ilẹ̀ eléso àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀ jẹ́ tèmi.+
-