Diutarónómì 10:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Wò ó, Jèhófà Ọlọ́run rẹ ló ni ọ̀run, àní ọ̀run àwọn ọ̀run,* pẹ̀lú ayé àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀.+ Jóòbù 41:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ta ló kọ́kọ́ fún mi ní ohunkóhun tí màá fi san án pa dà fún un?+ Tèmi ni ohunkóhun tó wà lábẹ́ ọ̀run.+ 1 Kọ́ríńtì 10:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 nítorí pé “Jèhófà* ló ni ayé àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀.”+
14 Wò ó, Jèhófà Ọlọ́run rẹ ló ni ọ̀run, àní ọ̀run àwọn ọ̀run,* pẹ̀lú ayé àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀.+
11 Ta ló kọ́kọ́ fún mi ní ohunkóhun tí màá fi san án pa dà fún un?+ Tèmi ni ohunkóhun tó wà lábẹ́ ọ̀run.+