Mátíù 6:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “Torí tí ẹ bá dárí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn èèyàn jì wọ́n, Baba yín ọ̀run náà máa dárí jì yín;+