Éfésù 4:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Àmọ́ ẹ jẹ́ onínúure sí ara yín, kí ẹ máa ṣàánú,+ kí ẹ máa dárí ji ara yín fàlàlà bí Ọlọ́run náà ṣe tipasẹ̀ Kristi dárí jì yín fàlàlà.+ Kólósè 3:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ẹ máa fara dà á fún ara yín, kí ẹ sì máa dárí ji ara yín fàlàlà,+ kódà tí ẹnikẹ́ni bá ní ìdí láti fẹ̀sùn kan ẹlòmíì.+ Bí Jèhófà* ṣe dárí jì yín ní fàlàlà, ẹ̀yin náà gbọ́dọ̀ máa ṣe bẹ́ẹ̀.+
32 Àmọ́ ẹ jẹ́ onínúure sí ara yín, kí ẹ máa ṣàánú,+ kí ẹ máa dárí ji ara yín fàlàlà bí Ọlọ́run náà ṣe tipasẹ̀ Kristi dárí jì yín fàlàlà.+
13 Ẹ máa fara dà á fún ara yín, kí ẹ sì máa dárí ji ara yín fàlàlà,+ kódà tí ẹnikẹ́ni bá ní ìdí láti fẹ̀sùn kan ẹlòmíì.+ Bí Jèhófà* ṣe dárí jì yín ní fàlàlà, ẹ̀yin náà gbọ́dọ̀ máa ṣe bẹ́ẹ̀.+