-
Máàkù 11:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Nígbà tí ẹ bá dúró láti gbàdúrà, ẹ dárí ji ẹnikẹ́ni tí ẹ bá ní ohunkóhun lòdì sí, kí Baba yín tó wà ní ọ̀run náà lè dárí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín jì yín.”+
-