-
2 Kíróníkà 25:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ni Amasááyà bá sọ fún èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ náà pé: “Ọgọ́rùn-ún (100) tálẹ́ńtì tí mo wá fún àwọn ọmọ ogun Ísírẹ́lì ńkọ́?” Èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ náà fèsì pé: “Jèhófà mọ bó ṣe máa fi èyí tó pọ̀ ju bẹ́ẹ̀ san án fún ọ.”+
-
-
Òwe 22:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Èrè ìrẹ̀lẹ̀ àti ìbẹ̀rù Jèhófà
Ni ọrọ̀ àti ògo àti ìyè.+
-