Sáàmù 103:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Bí yíyọ oòrùn ṣe jìnnà sí wíwọ̀ oòrùn,Bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe mú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa jìnnà sí wa.+ Àìsáyà 38:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Wò ó! Dípò àlàáfíà, ìbànújẹ́ ńlá ló bá mi;Àmọ́ torí ìfẹ́ tí o ní sí mi,*O pa mí mọ́ kúrò nínú kòtò ìparun.+ O ti ju gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ mi sí ẹ̀yìn rẹ.*+
17 Wò ó! Dípò àlàáfíà, ìbànújẹ́ ńlá ló bá mi;Àmọ́ torí ìfẹ́ tí o ní sí mi,*O pa mí mọ́ kúrò nínú kòtò ìparun.+ O ti ju gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ mi sí ẹ̀yìn rẹ.*+