1 Sámúẹ́lì 15:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Sámúẹ́lì wá sọ pé: “Ṣé àwọn ẹbọ sísun àti ẹbọ+ máa ń múnú Jèhófà dùn tó kéèyàn ṣègbọràn sí ohùn Jèhófà? Wò ó! Ṣíṣe ìgbọràn sàn ju ẹbọ,+ fífi etí sílẹ̀ sì sàn ju ọ̀rá+ àgbò; Sáàmù 40:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ẹbọ àti ọrẹ kọ́ ni ohun tó wù ọ́,*+Àmọ́ o la etí mi sílẹ̀ kí n lè gbọ́.+ O kò béèrè ẹbọ sísun àti ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀.+ Hósíà 6:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Nítorí pé ìfẹ́ tí kì í yẹ̀* ni inú mi dùn sí, kì í ṣe ẹbọÀti ìmọ̀ nípa Ọlọ́run dípò odindi ẹbọ sísun.+
22 Sámúẹ́lì wá sọ pé: “Ṣé àwọn ẹbọ sísun àti ẹbọ+ máa ń múnú Jèhófà dùn tó kéèyàn ṣègbọràn sí ohùn Jèhófà? Wò ó! Ṣíṣe ìgbọràn sàn ju ẹbọ,+ fífi etí sílẹ̀ sì sàn ju ọ̀rá+ àgbò;
6 Ẹbọ àti ọrẹ kọ́ ni ohun tó wù ọ́,*+Àmọ́ o la etí mi sílẹ̀ kí n lè gbọ́.+ O kò béèrè ẹbọ sísun àti ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀.+
6 Nítorí pé ìfẹ́ tí kì í yẹ̀* ni inú mi dùn sí, kì í ṣe ẹbọÀti ìmọ̀ nípa Ọlọ́run dípò odindi ẹbọ sísun.+