-
Sáàmù 94:3, 4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Ìgbà wo, Jèhófà,
Ìgbà wo ni àwọn ẹni burúkú ò ní yọ̀ mọ́?+
4 Wọ́n ń sọ̀rọ̀ yàùyàù, wọ́n sì ń sọ̀rọ̀ ìgbéraga;
Gbogbo àwọn aṣebi ń fọ́nnu nípa ara wọn.
-