Sáàmù 73:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nítorí mo jowú àwọn agbéraga*Nígbà tí mo rí àlàáfíà àwọn ẹni burúkú.+ Sáàmù 74:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ọlọ́run, ìgbà wo ni elénìní máa pẹ̀gàn rẹ dà?+ Ṣé ọ̀tá yóò máa hùwà àìlọ́wọ̀ sí orúkọ rẹ títí láé ni?+
10 Ọlọ́run, ìgbà wo ni elénìní máa pẹ̀gàn rẹ dà?+ Ṣé ọ̀tá yóò máa hùwà àìlọ́wọ̀ sí orúkọ rẹ títí láé ni?+