Sáàmù 57:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àwọn kìnnìún yí mi* ká;+Àárín àwọn tó fẹ́ fà mí ya ni mo dùbúlẹ̀ sí,Àwọn tí eyín wọn jẹ́ ọ̀kọ̀ àti ọfà,Tí ahọ́n wọn sì jẹ́ idà mímú.+ Sáàmù 59:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wo ohun tó ń tú* jáde lẹ́nu wọn;Ètè wọn dà bí idà,+Wọ́n ń sọ pé: “Ta ló ń gbọ́ wa?”+
4 Àwọn kìnnìún yí mi* ká;+Àárín àwọn tó fẹ́ fà mí ya ni mo dùbúlẹ̀ sí,Àwọn tí eyín wọn jẹ́ ọ̀kọ̀ àti ọfà,Tí ahọ́n wọn sì jẹ́ idà mímú.+