-
Sáàmù 64:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Wọ́n pọ́n ahọ́n wọn bí idà;
Wọ́n dojú ọ̀rọ̀ burúkú wọn kọni bí ọfà,
-
Òwe 25:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Bíi kùmọ̀ ogun àti idà àti ọfà tó mú
Ni ẹni tó ń jẹ́rìí èké sí ọmọnìkejì rẹ̀.+
-
-
-