Sáàmù 13:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ní tèmi, ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ ni mo gbẹ́kẹ̀ lé;+Àwọn iṣẹ́ ìgbàlà rẹ yóò máa mú ọkàn mi yọ̀.+ Sáàmù 147:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Inú Jèhófà ń dùn sí àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀,+Sí àwọn tó ń dúró de ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀.+