ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 52:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Ṣùgbọ́n màá dà bí igi ólífì tó gbẹ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀ nínú ilé Ọlọ́run;

      Ìfẹ́ Ọlọ́run tí kì í yẹ̀ ni mo gbẹ́kẹ̀ lé+ títí láé àti láéláé.

  • Sáàmù 147:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Inú Jèhófà ń dùn sí àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀,+

      Sí àwọn tó ń dúró de ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀.+

  • 1 Pétérù 5:6, 7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Torí náà, ẹ rẹ ara yín sílẹ̀ lábẹ́ ọwọ́ agbára Ọlọ́run, kó lè gbé yín ga ní àkókò tó yẹ,+ 7 ẹ máa kó gbogbo àníyàn* yín lọ sọ́dọ̀ rẹ̀,+ torí ó ń bójú tó yín.*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́