1 Sámúẹ́lì 23:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Lẹ́yìn náà, àwọn ọkùnrin Sífù lọ sọ́dọ̀ Sọ́ọ̀lù ní Gíbíà,+ wọ́n sọ pé: “Ṣebí tòsí wa ni Dáfídì fara pa mọ́ sí,+ ní àwọn ibi tó ṣòroó dé ní Hóréṣì,+ lórí òkè Hákílà,+ tó wà ní gúúsù* Jéṣímónì.*+ 1 Sámúẹ́lì 26:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Nígbà tó yá, àwọn ọkùnrin Sífù+ wá sọ́dọ̀ Sọ́ọ̀lù ní Gíbíà,+ wọ́n sọ pé: “Dáfídì fara pa mọ́ sórí òkè Hákílà tó dojú kọ Jéṣímónì.”*+
19 Lẹ́yìn náà, àwọn ọkùnrin Sífù lọ sọ́dọ̀ Sọ́ọ̀lù ní Gíbíà,+ wọ́n sọ pé: “Ṣebí tòsí wa ni Dáfídì fara pa mọ́ sí,+ ní àwọn ibi tó ṣòroó dé ní Hóréṣì,+ lórí òkè Hákílà,+ tó wà ní gúúsù* Jéṣímónì.*+
26 Nígbà tó yá, àwọn ọkùnrin Sífù+ wá sọ́dọ̀ Sọ́ọ̀lù ní Gíbíà,+ wọ́n sọ pé: “Dáfídì fara pa mọ́ sórí òkè Hákílà tó dojú kọ Jéṣímónì.”*+