Sáàmù 43:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 43 Ṣe ìdájọ́ mi, Ọlọ́run,+Gbèjà mi+ níwájú orílẹ̀-èdè aláìṣòótọ́. Gbà mí lọ́wọ́ ẹlẹ́tàn àti aláìṣòdodo.
43 Ṣe ìdájọ́ mi, Ọlọ́run,+Gbèjà mi+ níwájú orílẹ̀-èdè aláìṣòótọ́. Gbà mí lọ́wọ́ ẹlẹ́tàn àti aláìṣòdodo.