Sáàmù 35:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Jèhófà, gbèjà mi níwájú àwọn tó ń ta kò mí;+Dojú ìjà kọ àwọn tó ń bá mi jà.+ Òwe 22:22, 23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Má ja tálákà lólè torí pé kò ní lọ́wọ́,+Má sì fojú aláìní gbolẹ̀ ní ẹnubodè,+23 Nítorí Jèhófà fúnra rẹ̀ yóò gba ẹjọ́ wọn rò+Yóò sì gba ẹ̀mí* àwọn tó lù wọ́n ní jìbìtì.
22 Má ja tálákà lólè torí pé kò ní lọ́wọ́,+Má sì fojú aláìní gbolẹ̀ ní ẹnubodè,+23 Nítorí Jèhófà fúnra rẹ̀ yóò gba ẹjọ́ wọn rò+Yóò sì gba ẹ̀mí* àwọn tó lù wọ́n ní jìbìtì.